Lauren Parkerway

Ọrọ kàbìtì: Agbénigbowó sekú pa ọ̀gá ilé ìtura, ẹni méjì mìíràn, lẹ́yìn tí wọ́n gba N5m

A ṣe ìrìn-àjò lọ sí ilé ìtura Tana Suites ní ìlú Ògbómọ̀ṣọ́ láti bá ẹ̀gbọ́n Bàbá Olúgbénga Owólabí tó ni ilé ìtura náà lẹ́nu wò lẹ́yìn tí àwọn agbénigbowó ṣekú pa á àti àwọn méjì mìíràn lẹ́yìn tí wọ́n gba mílíọ̀nù márùn-ún náírà gẹ́gẹ́ bí owó ìdásílẹ.

Read More

Leave a Comment

Your email address will not be published.

Generated by Feedzy
Scroll to Top